Maku 5:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wá kìlọ̀ fún wọn gan-an pé kí wọn má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀. Ó ní kí wọn wá oúnjẹ fún ọmọde náà kí ó jẹ.

Maku 5

Maku 5:36-43