Maku 5:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá fa ọmọde náà lọ́wọ́, ó wí fún un pé, “Talita kumi” ìtumọ̀ èyí tíí ṣe, “Ìwọ ọmọde yìí, mo wí fún ọ, dìde.”

Maku 5

Maku 5:31-43