Maku 5:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “Arabinrin, igbagbọ rẹ ti mú ọ lára dá. Máa lọ ní alaafia, o kò ní gbúròó àìsàn náà mọ́.”

Maku 5

Maku 5:29-41