Maku 5:28 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ó sọ ninu ara rẹ̀ pé, “Bí ó bá jẹ́ aṣọ rẹ̀ ni mo lè fi ọwọ́ kàn, ara mi yóo dá.”

Maku 5

Maku 5:20-31