Maku 5:23 BIBELI MIMỌ (BM)

ó bẹ̀rẹ̀ sí bẹ̀ ẹ́. Ó ní, “Ọmọdebinrin mi ń kú lọ, wá gbé ọwọ́ lé e, kí ó lè yè.”

Maku 5

Maku 5:19-28