Maku 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Satani bá gbógun ti ara rẹ̀, tí ó ń bá ara rẹ̀ jà, kò lè fi ẹsẹ̀ múlẹ̀, a jẹ́ pé ó parí fún un.

Maku 3

Maku 3:25-33