Maku 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Farisi wí fún un pé, “Wò bí wọn ti ń ṣe ohun tí kò tọ́ láti ṣe ní Ọjọ́ Ìsinmi!”

Maku 2

Maku 2:16-27