Maku 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n wo inú ibojì, wọ́n rí ọdọmọkunrin kan tí ó jókòó ní apá ọ̀tún wọn, tí ó wọ aṣọ funfun. Wọ́n bá ta gìrì.

Maku 16

Maku 16:1-9