Maku 15:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹnu ya Pilatu pé Jesu ti yára kú! Ó pe ọ̀gágun, ó bèèrè bí Jesu ti kú tipẹ́.

Maku 15

Maku 15:39-47