Maku 15:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ogun bá mú un lọ sí inú agbo-ilé tí ààfin gomina wà. Wọ́n pe gbogbo àwọn ọmọ-ogun yòókù,

Maku 15

Maku 15:7-21