Maku 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu wí fún wọn pé, “Ẹ fi í sílẹ̀, kí ni ẹ̀ ń yọ ọ́ lẹ́nu sí? Ohun rere ni ó ṣe sí mi.

Maku 14

Maku 14:1-16