Maku 14:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí alufaa ati gbogbo Ìgbìmọ̀ ń wá ẹ̀rí tí ó lòdì sí Jesu, kí wọ́n baà lè pa á, ṣugbọn wọn kò rí.

Maku 14

Maku 14:49-62