Maku 14:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún wọn pé, “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ mi tí a fi dá majẹmu, ẹ̀jẹ̀ tí a ta sílẹ̀ fún ọpọlọpọ eniyan.

Maku 14

Maku 14:14-26