Maku 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń jẹun, Jesu mú burẹdi, ó gbadura sí i, ó bù ú, ó fún wọn. Ó ní, “Ẹ gbà, èyí ni ara mi.”

Maku 14

Maku 14:16-29