Maku 13:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo wá rán àwọn angẹli láti lọ kó àwọn àyànfẹ́ jọ láti igun mẹrẹẹrin ayé, láti òpin ayé títí dé òpin ọ̀run.

Maku 13

Maku 13:25-30