Maku 13:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Kí alágbàro ní oko má ṣe dúró mú ẹ̀wù rẹ̀ tí ó bọ́ sílẹ̀.

17. Ọjọ́ ìṣòro ni ọjọ́ náà yóo jẹ́ fún àwọn aboyún ati àwọn tí ó ń fún ọmọ lọ́mú ní àkókò náà.

18. Kí ẹ gbadura kí ó má jẹ́ àkókò tí òtútù mú pupọ.

Maku 13