Maku 12:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dáhùn pé, “Èyí tí ó ṣe pataki jùlọ nìyí, ‘Gbọ́, Israẹli, Oluwa Ọlọrun wa nìkan ni Oluwa.

Maku 12

Maku 12:24-30