Maku 12:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí àwọn òkú bá jinde, kò sí pé à ń gbé iyawo tabi à ń fa obinrin fún ọkọ, ṣugbọn bí àwọn angẹli ọ̀run ni wọn yóo rí.

Maku 12

Maku 12:23-34