Maku 11:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá dá Jesu lóhùn pé, “Àwa kò mọ̀.”Nígbà náà ni Jesu sọ fún wọn pé, “Èmi náà kò ní sọ irú àṣẹ tí mo fi ń ṣe àwọn nǹkan wọnyi fun yín.”

Maku 11

Maku 11:30-33