Maku 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di òwúrọ̀, bí wọ́n ti ń kọjá lọ, wọ́n rí i tí igi ọ̀pọ̀tọ́ àná ti gbẹ patapata láti orí dé gbòǹgbò.

Maku 11

Maku 11:13-29