Maku 10:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ eniyan ń bá a wí pé kí ó panu mọ́. Ṣugbọn sibẹ ó túbọ̀ ń kígbe pé, “Ọmọ Dafidi! Ṣàánú mi.”

Maku 10

Maku 10:39-52