Maku 10:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọpọlọpọ tí ó jẹ́ ẹni iwájú yóo di èrò ẹ̀yìn, àwọn èrò ẹ̀yìn yóo wá di ẹni iwájú.”

Maku 10

Maku 10:27-36