Maku 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Jesu gbé àwọn ọmọde náà lọ́wọ́, ó gbé ọwọ́ lé wọn, ó sì súre fún wọn.

Maku 10

Maku 10:11-21