Maku 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wà níbẹ̀ fún ogoji ọjọ́ tí Satani ń dán an wò. Ààrin àwọn ẹranko ni ó wà, ṣugbọn àwọn angẹli ń ṣe iranṣẹ fún un.

Maku 1

Maku 1:6-23