Luku 9:60 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu sọ fún un pé, “Jẹ́ kí àwọn òkú máa sin òkú ara wọn. Ìwọ ní tìrẹ, wá máa waasu ìjọba Ọlọrun.”

Luku 9

Luku 9:54-62