Luku 9:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń lọ lọ́nà, ẹnìkan wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó ní, “N óo máa bá ọ lọ sí ibikíbi tí o bá ń lọ.”

Luku 9

Luku 9:47-62