Luku 9:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Àríyànjiyàn kan bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu lórí pé ta ló ṣe pataki jùlọ láàrin wọn.

Luku 9

Luku 9:37-50