Luku 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

(Àwọn ọkunrin ninu wọn tó bíi ẹgbẹẹdọgbọn (5,000).)Ó bá sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Ẹ jẹ́ kí wọ́n jókòó ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ bí araadọta.”

Luku 9

Luku 9:11-24