Luku 8:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Jesu gbọ́, ó dá a lóhùn pé, “Má bẹ̀rù, ṣá gbàgbọ́, ara ọmọ rẹ yóo dá.”

Luku 8

Luku 8:42-56