Luku 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ eniyan ń wọ́ tẹ̀lé e lẹ́yìn láti ìlú dé ìlú. Ó wá fi òwe bá wọn sọ̀rọ̀ pé:

Luku 8

Luku 8:1-8