Luku 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan bá sọ fún un pé, “Ìyá rẹ ati àwọn arakunrin rẹ dúró lóde, wọ́n fẹ́ fi ojú kàn ọ́.”

Luku 8

Luku 8:14-22