Luku 7:45 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò fi ìfẹnukonu kí mi. Ṣugbọn obinrin yìí kò dẹ́kun láti fi ẹnu kan ẹsẹ̀ mi láti ìgbà tí mo ti wọ ilé.

Luku 7

Luku 7:43-50