Luku 7:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu sọ fún un pé, “Simoni, mo fẹ́ bi ọ́ léèrè ọ̀rọ̀ kan.”Simoni ní, “Olùkọ́ni, máa wí.”

Luku 7

Luku 7:35-43