Luku 7:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn Farisi ati àwọn amòfin kọ ìlànà Ọlọrun fún wọn, wọn kò ṣe ìrìbọmi ti Johanu.

Luku 7

Luku 7:27-31