Luku 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó gbọ́ nípa Jesu, ó rán àwọn àgbààgbà Juu kan sí i pé kí wọn bá òun bẹ̀ ẹ́ kí ó wá wo ẹrú òun sàn.

Luku 7

Luku 7:1-9