Luku 7:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ó bá lọ, ó fi ọwọ́ kan pósí. Àwọn tí wọ́n gbé pósí bá dúró. Ó bá sọ pé, “Ọdọmọkunrin, mo sọ fún ọ, dìde.”

Luku 7

Luku 7:7-20