Luku 6:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá tọrọ nǹkan lọ́wọ́ yín, ẹ fún un. Bí ẹnìkan bá mú nǹkan yín, ẹ má bèèrè rẹ̀ pada.

Luku 6

Luku 6:21-39