Luku 6:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ṣé ẹ kò ì tíì ka ohun tí Dafidi ṣe nígbà tí ebi ń pa òun ati àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀?

Luku 6

Luku 6:1-7