Luku 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Jesu lọ sí orí òkè, ó lọ gbadura. Gbogbo òru ni ó fi gbadura sí Ọlọrun.

Luku 6

Luku 6:11-19