Luku 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹnu yà á ati gbogbo àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ fún ọpọlọpọ ẹja tí wọ́n rí pa.

Luku 5

Luku 5:1-13