Luku 5:38-39 BIBELI MIMỌ (BM)

38. Ṣugbọn ninu àpò awọ titun ni wọ́n ń fi ọtí titun sí.

39. Kò sí ẹni tí ó bá ti mu ọtí tí ó mú, tíí fẹ́ mu ọtí àṣẹ̀ṣẹ̀pọn. Nítorí yóo sọ pé, ‘Ọtí tí ó mú ni ó dára.’ ”

Luku 5