Luku 5:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Àwọn tí ara wọn le kò nílò oníṣègùn, bíkòṣe àwọn tí ara wọn kò dá.

Luku 5

Luku 5:24-38