Luku 5:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹsẹkẹsẹ ó dìde lójú gbogbo wọn, ó gbé ibùsùn rẹ̀, ó lọ sí ilé rẹ̀, ó ń yin Ọlọrun lógo.

Luku 5

Luku 5:22-31