Luku 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rí àwọn ọkọ̀ meji létí òkun. Àwọn apẹja ti kúrò ninu àwọn ọkọ̀ yìí, wọ́n ń fọ àwọ̀n wọn.

Luku 5

Luku 5:1-4