Luku 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu pada láti odò Jọdani, ó kún fún Ẹ̀mí Mímọ́. Ẹ̀mí bá darí rẹ̀ lọ sí aṣálẹ̀.

Luku 4

Luku 4:1-5