Luku 24:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń sọ àwọn nǹkan wọnyi lọ́wọ́, Jesu alára bá dúró láàrin wọn. Ó ní, “Alaafia fun yín.”

Luku 24

Luku 24:32-45