Luku 24:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá bi í pé, “Bíi kí ni?”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Àwọn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí Jesu ará Nasarẹti ni. Wolii ni, iṣẹ́ rẹ̀ ati ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì fi agbára hàn níwájú Ọlọrun ati gbogbo eniyan.

Luku 24

Luku 24:15-23