Luku 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń bá ara wọn jíròrò, tí wọn ń bá ara wọn jiyàn, Jesu alára bá súnmọ́ wọn, ó ń bá wọn rìn lọ.

Luku 24

Luku 24:10-19