Luku 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní kutukutu òwúrọ̀ ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, wọ́n wá sí ibojì, wọ́n mú òróró olóòórùn dídùn tí wọ́n ti tọ́jú lọ́wọ́.

Luku 24

Luku 24:1-5