Luku 23:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọ̀gágun náà rí ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó yin Ọlọrun lógo, ó ní, “Lóòótọ́, olódodo ni ọkunrin yìí.”

Luku 23

Luku 23:46-52